Back to life, back to reality Back to life, back to reality Back to life, back to reality Back to the here and now, oh-yeah On a normal day, them no fit touch my energy (Kúrò n be) Agba, ab'orí n ta yin? (L'Eko) If I no get money na disability Baba o, so forget mo ma ṣa e blocking Má lọ sa o Be'ri fun oga o Agbabiaka o Gbá update k'ole pa'wo Won le, won o ba o Take them do yanga o (Kúrò n be) Má lọ wa o Ọmọ ọba Jesu, iwo ọkọ ashawo Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn Na my fruit of labour ni Everyday, I dey spray money To ba tele mi lo, my lady You go see say, aye nbe l'ókè (L'Eko) Mo kan gbé wan de be o (Okay now) Falila ke'tan, mo de fẹ fé e be yen o Every woman give me special treatment Wọn fi mi'le ni gba kan-kan-kan-kan-kan Má lọ sa o Be'ri fun oga o Agbabiaka o Gbá update k'ole pa'wo Won le, won o ba o Take them do yanga o (Nibo, nibo) Má lọ wa o Ọmọ ọba Jesu, iwo ọkọ ashawo Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn (Agbabiaka, oh) Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn (Mm) Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn Back to life, back to reality Back to life, back to reality Back to life, back to reality Back to the here and now, oh-yeah Má lọ sa o Be'ri fun oga o Agbabiaka o (Ka o) Gbá update k'ole pa'wo (Pa'wo) Won le, won o ba o (Ba o) Take them do yanga o (Kúrò n be) Má lọ wa o Ọmọ ọba Jesu, iwo ọkọ ashawo ('Shawo)